Transcript · Yoruba → English
Yoruba → English transcript
Look at it. You have seen it. Look at me well. It hurts me that your
mother is only a soap- washer.
Your mother is as dark as I am now.
They are saying the child that was born for me looks like this.
The place where we went for that case, we got to the station.
The officers at the station were mocking me, saying that... Inside the black shell,
white fluid is what usually comes out. Is it really true? Help me look at it,
help us resolve this matter.
End of transcript · 92 words · machine translated
Original transcript (Yoruba)
Ẹ wo o. Ẹ ti ri i. Ẹ wo mi daadaa o. O dun mi pe iya ẹ fọṣẹlọwọ ni. Iya ẹ dudu bi temi bayii. Wọn wa ni pe ọmọ to bi fun mi leleyi. Ibi ta ti lọ fẹjọ yẹn, a wa de station. Awọn station wa n pa owe fun mi pe... Inu koko dudu, lẹkọ funfun ti ma n jade. Ṣe lootọ ni? Ẹ ba mi wo o,
ẹ ba wa da si ọrọ yii o.