Yoruba → English transcript
What is all that commotion? Huh?
When you told me to bring your hoe, the clearing... the butter clearing,
the whole farm turned white.
The whole farm is white. Ah. Ah, ah. It is harmattan now.
How many times do I have to tell you?
It is harmattan. Ah, ah, and you are scolding me.
Is it because of that… Is harmattan not affecting you too?
Even all your lips are white.
The Harmattan has really hit you now. Ah. What is it?
I said it is Harmattan. How many times do I have to say it?
Please. You are useless. Forbidden…
End of transcript · 102 words · machine translated
Original transcript (Yoruba)
Kí ni gbogbo radarada yẹn? Ẹn? Nígbà tí o ní kí n mú ẹpon rẹ, àgbókò... àgbókò bọ́ta, gbogbo oko wá funfun. Gbogbo orí oko wá funfun. Ah. Ah ah. Ọyẹ́ ni now. Ẹ̀melòó ni mo fẹ́ sọ fún ọ? Harmattan ni. Ah ah, o sì ń bú mi. Ṣé torí pé sọ̀rọ̀... Ṣé ọyẹ́ ò gbé ọ náà ni? Ewé gbogbo ìbú rẹ ló ń funfun. Ọyẹ́ gbé ọ náà lọ́lúbọ̀ now. Ah. Kí ló dé?
Ewé gbogbo ìbú rẹ ló ń funfun. Ọyẹ́ gbé ọ náà lọ́lúbọ̀ now. Ah. Kí ló dé? Mo ní Harmattan ni. Ẹ̀melòó ni mo fẹ́ wí? Dakun. Olòṣì ni ọ́. Èwọ̀...