Jídé fún obìnrin mẹ́ta lóyún láàárín oṣù mẹ́rin
Jide fun obirin meta ni oyun po leekan.
Laarin osu merin, o fun obirin meta po ni oyun. Lo ba ru oyun de. Wipe Jide lo
fun awon ni oyun. Kini mo fe se? Mo gba naa ni. Nigba ti awon yen bimo,
meji ninu awon obirin ti Jide fun loyun...
...won wa da awon omo yen si mi ni orun. Ikan ninu won lo gbe omo e lo.
Mo wa n bo Jide. Mo n bo ara iwaju. Mo n bo awon aburo won to ku.
Mo tun wa n bo omo Jide meji, t'obirin... obirin... awon to meji bi fun.
Bo ti e je pe iketa, o ti gbe omo e lo.
End of transcript · 114 words
Transcribed with TranslateMom. Paste any video link to get subtitles and a transcript in your language.