Ìwà Mùsùlùmí, ààbò Nàìjíríà àti pípè Ahmadiyya ní kèfèrí

Iwọ Musulumi, fi iwa kọ ẹsin rẹ ki ilu da. Iwọ

Musulumi, fi iwa kọ ẹsin rẹ ki ilu da. Iwọ Musulumi,

ma fi iwa rẹ da rogbodiyan kalẹ sinu ilu...

...pẹlu ohun pe a n pariwo Jihad, a n pariwo

Sharia, a n pariwo kini kan, awọn nkan ta n

wi niyẹn. Ma fi iwa rẹ... Ti iwọ ba wa ri pe

iwa rẹ, moral ta wa n pariwo ni. Ti iwọ ba ni

immorality ati iniquity... Oun ni o bọta ko

sọ. Ta wa n ṣe yi, security kan... ko lọ gbọ

gbogbo nkan ta n wi. To ba jẹ pe awa la fẹ protect

security in Nigeria... Wipe Musulumi si Musulumi,

ma wi pe Musulumi kan ti o ba si ninu ijọ rẹ,

ma wi pe o ni ki un lẹyin. Ma pe ni keferi.

Nitori pe ẹnikan o... ẹ ha... ko wa pe ni keferi.

Nitori pe ẹnikan o ni irungbọn, ma wa pe ni

keferi. Nitori pe ẹnikan o wẹ lawani, ko ma

wa pe ni keferi. Ka

wa wi yun ni, ka ma wa pe ni keferi... Nitori

pe Ahmadiyya kan n bẹ, keferi ni. Iwọ lo n keferi

ni. Ohun ta n wi nu un.

End of transcript · 202 words

Transcribed with TranslateMom. Paste any video link to get subtitles and a transcript in your language.

iPhone app Translate videos on your iPhone Paste a TikTok, Instagram or X link, add subtitles in your language and save the video to Photos.

Made with TranslateMom

TranslateMom transcribes and translates videos from X, TikTok, YouTube and Instagram. Paste a link and you get a page like this one, in your language.

© 2026 TranslateMom · AI video translation and subtitles Transcripts Sources Pricing Legal