Nigeria's Oil Wealth Discussion

Orílè-èdè Nàìjíríà àì kí ń ṣe ọlọ́rọ̀ epo.

Nàìjíríà o kín ń ṣe oil rich nation.

Mo fẹ jẹ́ kí gbogbo wa mọ bẹ́ẹ̀ pé ilẹ̀ Nàìjíríà àì kí ń

ṣe oil rich nation. Í pé ká wá sọ í pé, eh, ìlú wa

ọlọ́rọ̀ epo ni wa. A ní, eh, ọrọ epo gan, a

ni.

Àná kan manage ni. Ọrọ epo ni ohun tó ń pè ní ọrọ

epo.

Oil rich nation, Nàìjíríà ò sínbẹ̀.

Ìjiyàn tí mo fẹ́ mú wá nìyẹn, àmọ́ ẹ máa bá mi bọ̀ kí ó lè jọ yé

gbogbo wa.

Sẹ́rí nínú ìjiyàn yìí, lóòótọ́ Nàìjíríà ní epo tí a

ń gbọ́n. Èyí tí a ń gbọ́n lójoojúmọ́.

Ó wà ní South South, àwọn South South, Niger Delta sé yẹn.

Sé wá rí epo yìí, tá bá ní ká ṣe, ẹ mọ pé Nàìjíríà ò ṣe ọlọ́rọ̀

epo. Í pé a ní ọrọ̀ epo, ìyá n t'óru, à ń ṣe ọlọ́rọ̀ epo.

Gẹ́gẹ́ bí àwọn èèyàn ṣe máa ń sọ pé, "a dẹ̀ lé epo, owó epo wá, owó epo

wá", ẹjẹ́ má máa pa irọ́ fúnra wa. A ò ṣe ọlọ́rọ̀

epo. Àwa náà kan wà nínú àwọn ìlú tó lé epo ni.

Àti ká wá nǹkan mí bí owó orí, bí àwọn nǹkan mí.

Ìdí ni pé lọ́rílèèdè Nàìjíríà, ẹ jẹ́ kí n ṣe báyìí pé

epo tí à ń rí

ní ojúmọ́, average, wọn ṣe, ó máa ń wálẹ̀ ó máa ń lọ

sókè. Nígbà tí a yẹ̀ wò ó jẹ́, eh, one

point five million barrel per day up to one point

seven million barrel per day. Barrel ni wọ́n fi ń ṣe kó

ṣe gallon. Wọ́n wá ní one point five million àbí one

point-- láàrin

one point five sí one point seven million barrel per day.

Ẹ wá jẹ́ ká di one point seven. Ó máa ń wálẹ̀ jù bẹ́ẹ̀ lọ́gbà mí

òpápa ju lọ láyé àwọn Buhari ìgbà náà, ìgbà tí wọ́n sì ń jí

epo wà tó ń ta fáwọn ìlú òkè òkun.

Nàììjíríà ń rí epo one point fi-- one point seven million

barrel per day. Iyẹn ni ojúmọ́ kan.

Saudi Arabia,

àwọn ń gbọ́ epo nílùú wọn, epo tó jẹ́ six million two hundred

and-- six point two hundred and thirty eight million per day.

Ni Saudi Arabia six point two hundred and thirty eight million

barrel per day ní ọjọ́ kan. Óun ni wọ́n ń gbọ́n.

Sé ẹ ń gbọ́ mi? Àwọn Qatar, ìlú Qatar, àwọn

máa ń gbọ́n, wọ́n ń gbọ́n epo five hundred

and eighty thousand

barrel ní ọjọ́ kan. Qatar wọ́n ń gbọ́n epo five hundred

and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan.

Mo mọ̀ mọ̀ mú ìlú tó ní epo púpọ̀. Mo tún mú ìlú tí ò gbọ́n

púpọ̀ tó wá wá. Kí àgbọ́yé yẹn kó lè dá,

kó lè gbo-- kó lè yé gbogbo wa. ẹ rí UAE àwọn produce

three point eight million barrel per day.

Epo tí wọ́n ń rí lójúmọ́ barrel three point eight million barrel

per day. Sé o ti yé yin? ẹ wá jẹ́ ká ṣe ìṣirò

ẹ̀. Sé ẹ rí ilẹ̀, orílè-èdè Nàìjíríà, a ní èèyàn two

hundred and forty four million.

Two hundred and forty four million the-- ó wà documented ìbáyìí.

Tẹ bá wò wípé a jẹ́ iye èèyàn tó ń gbé nílùú wa, t'a jọ mọ

ìlú two hundred and forty four million people.

A dẹ̀ ń rí epo

one point seven million

per day ní ọjọ́ kan. Saudi Arabia tó ń rí, tó

ní epo

six point two hundred and thirty eight million barrel

lójúmọ́ kan. Àwọn ní population, èròlú wọn

ó jẹ́ thirty five point two million.

Sé ẹ ń gbọ́ o? Thirty five point two million.

Díẹ̀ lọ bí i Jekọ lọ.

Qatar tó ń rí

epo five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan.

Five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan. Ẹ mọ̀ pé ko tó one million.

Ní ìlú wọn, wọ́n jẹ́ three point two million.

Àwọn aráàlú wọn, wọ́n jẹ́ three point two million.

Sé wá rí UAE, United Arab Emirate, mo mọ̀ mọ̀ mú àwọn tí ẹ máa ń fi wa

wé yẹn, mo mọ̀ mọ̀ mú wọn wá ni. Í pé bí àwọn yẹn owó epo lọ́ n fi ṣe bá

kẹlé gba wa ayé. Ìdí--

àwọn UAE ní epo three point eight million lọ ń

produce barrel lọ.

Iye èèyàn tó wà nílùú wọn jẹ́ eleven point six million.

Iye èèyàn tó wà nílùú wọn ó jẹ́ eleven point six

million. Sé wá ń gbọ́? ẹ wá jẹ́ ká wá sí Nàìjíríà.

A ń rí epo one point seven million.

Ẹ jẹ́ ká wá pín one point seven million yẹn ká fi divide the two hundred and

forty four million.

Barrel, iye barrel mélòó ló kan èèyàn kankan.

Ẹ jẹ́, òun ni mo kọ. Zero point zero zero six

nine

barrel. Zero point

zero zero six nine barrel fún èèyàn kan.

Ṣọ̀rọ̀ yẹn ye.

Òun ni fún èèyàn kan.

Saudi, ilẹ̀ Saudi Arabia

tí a bá ṣí epo tó ń rí six point two hundred and thirty

eight million barrel ní ọjọ́ kan, òun dè ní

èrò tó ń gbé lù àwọn ará ìlú ẹ jẹ́ thirty two-- thirty five point two million.

Iye tí Saudi, iye tí ara ìlú kọ̀ọ̀kan máa ń rí ó jẹ́

zero

point one hundred and seventy eight.

Zero point one hundred and seventy eight fún èèyàn kan.

Qatar, iye tó ó máa ń rí fún èèyàn kan ó jẹ́ zero

point one

eighty one fún èèyàn kan. Zero point one eighty one.

Sé ẹ rí Qatar yẹn tí ẹ bá gbàgbé ọmọ ló ń produce, ó ń rí epo

five hundred and eighty thousand barrel.

Population wá jẹ́ three point two million.

Tá bá wá ṣí five hundred and eighty tá a fi pín, divide rẹ̀

sí three point two million àwọn aráàlú ẹ.

Epo tí ó ń rí ní Qatar èèyàn kan,

ohun tó máa ń kọ èèyàn kan ni zero point one eighty one barrel fún èèyàn

kan. UAE ló ń rówó jù. Torí UAE yẹn,

òun, epo tí UAE ń rí three point eight million

barrel

ló ń rí lójúmọ́. Aráàlú ẹ lẹ́ẹ̀ jẹ́ eleven point six

million.

Ohun tí UAE wà ń rí ò jẹ́ zero point three two seven ní èèyàn kan máa ń rí.

Iyẹn barrel èèyàn kan. Ẹ jẹ́ wá mú báyìí.

Iye tí èèyàn kan ní Nàìjíríà tí ó máa ń rí, tá bá pín eyi,

owó, eh, epo tá ń rí sórí gbogbo àwọn tó bá ta,

tá bá pín

Èèyàn kan máa rí

naira and forty five naira.

Iyẹn fún epo zero point zero zero six nine yẹn.

Baba wa ojúmọ̀ bá ṣe ń ta yẹn ká máa wá pín fún aráàlú kan.

Iye tó kun èèyàn kan. Nine point-- eh, nine hundred and

forty five naira ló kun èèyàn kan. Nine hundred and

forty five naira.

Nínú ìrìn tó orí ọlọ́pa wà níbẹ̀, wọ́n máa san owó oṣù.

Àwọn tó ń dáàbò bọ̀ ẹ, nine hundred and forty five naira.

Gbogbo ìlú bọ́ ṣe ń to, rédíò, gbogbogbà, gbogbo awo, àwọn

nǹkan yìí tí ìjọba ń ṣe

àbí wọ́n ṣe, iṣẹ́ ìjọba kankan ò dọdú etí tí tó ń rìn.

Se nine hundred and forty five òní.

Se wá rí ní United Arab Emirate, owó tí èèyàn kan máa

rí,

owó tí èèyàn kan máa rí ó jẹ thirty one

point eighty two dollar. Ka ní thirty two dollar. Èèyàn kan máa rí.

Tọ bá pín epo tó ń rí lójúmọ́, tó bá gbọ́ sórí èèyàn kankan,

ẹni kankan á gba thirty two dollar.

Taa bá ṣe thirty two dollar yẹn sí náírà, ó máa jẹ forty two

thousand three hundred and thirty fún èèyàn kan.

Forty two thousand three hundred and thirty fún èèyàn kan.Ẹ jọ,

tọ́ mọ̀lú wọn ò bá

ṣiṣẹ́, tó bá fún lówó, ṣe ó tó bẹ́ àbí ò tó bẹ́?

Wọ́n dẹ̀ tún ní gold, wọ́n tún láwọn ọrọ̀ ajé ni.

Kẹ́ ẹ lè mọ̀ wípé àwọn ìlú tó ní ọrọ̀ epo nìyẹn.

Epo tá ń gbọ́ lẹ̀ ń wò pé ó pọ̀. Ẹ̀wọ̀ yẹ èèyàn

tí ìjọba fẹ́ katà fún, tó fẹ́ bù katà fún.

Ẹ̀wọ̀ yẹ bù katà tó wà nínú ìjọba wa.

Ẹ̀wọ̀ yẹ bù katà ìhun tí ìjọba wa ń gbọ́ iye

èrò tó fẹ́ gbọ́tí ẹ̀. ìdí nìyẹn tó wọ̀nyí ò ṣe ná.

Ẹ wá ní òkè, ìgbà tí wọ́n ń wá, tí wọ́n wá jẹ́ owó tó kàn èèyàn kan,

epo kan pàá bàárẹ́. Ó wá jẹ́ nine, ní Nigeria ni bíí nine

hundred and forty five naira. ẹ wá ní kí wọ́n máa subsidize rẹ̀,

kí wọ́n máa fowó

òkun pa síi.Ẹ jọ, ọ̀fẹ́ ló máa jẹ yẹn.

Iṣẹ́ tó ní ẹ fẹ́ ṣe fún gbogbo wa nínú ìlú u wa ó pọ̀.

Taa bá ṣe owó epo yẹn lórí èèyàn kankan, ó yá.

Tọ bá fún ògbe èèyàn lówó yẹn, iṣẹ́ tó fẹ́ ṣe nínú ìlú ń kọ ìdí tó

ṣe le láti san owó ìkúnpa owó epo fún wa lórílẹ̀èdè

Nigeria ni mo ṣàlàyé yìí. Ẹ̀yin èèyàn, mí à jẹ́ kí ẹnìkan wá,

kó má ní òun á dá owó epo padà. Irọ̀lẹ́ ni ìyẹn ń pa.

Ó kàn máa kó wa sí gbèsè. Ó máa kó wa sí gbèsè ni.

Gbèsè tá tú máa máa san òní Tinubu san lọ́wọ́, ó ń yá ó fi ń ṣe ọ̀nà.

Ọ̀nà tó ń rí táwọn ń dá tí ògbe ń dá làwọn

òṣìṣẹ́ àwọn ilé iṣẹ́ ṣe wá láti ìta ná wá ń dá ilé iṣẹ́ lẹ̀.

Wọn ò ní pàrí iṣẹ́ yẹn tó bá bẹ̀rẹ̀ tọ́ sí ibi padà. Gbogboṣé wọn ò ní rówó ṣe.

Wọn ò ní rówó ṣe mọ́. Àlàyé tí mo ní mú wá ni pé ilẹ̀ Nàìjíríà

o,

a ò ṣe ọlọ́rọ̀ epo. Àwa náà ní epo. Epo kan ń dá sí

owó tí a ń rí ni. So kò ṣe pé ká má san owó orí.

Kò yẹ bẹ́. Fún ètò ààbò àti ìlú tó péye kò yẹ pé ká

má

san owó orí. Àlàyé tí mo ní mú wá. Ẹ má bíi mo wà very very

emotional torí mo má ń ka comment, mo mọ̀ pé à,

ohun tó pọ̀ tí ò yẹ àwọn èèyàn mi,

ó pọ̀ gan. Jẹ́ kí ń clear, kí i ní kí ń la.

Ẹ jẹ́ àwọn èèyàn ṣe, ẹ bá mi like ẹ. Àbí kílé ni náà tú rí fíìmù tí mo sọ.

Ṣé Nàìjíríà jẹ́ ọlọ́rọ̀ epo pẹ̀lú ìṣirò tí mo gbé wá léyìí, tí mo gbé wá

yìí? Tẹ́ ì bá, tẹ́ ì bá ṣe èrò, ẹ jọ, ẹ jẹ́ ká mọ̀ ní comment section.

Ẹ bá like, ẹ share, ẹ follow. Ẹ má gbàgbé láti subscribe ní YouTube àti

Facebook. Ẹ ṣe

End of transcript · 1,803 words

iPhone app Translate videos on your iPhone Paste a TikTok, Instagram or X link, add subtitles in your language and save the video to Photos.

Read any video in your language

Paste a link from X, TikTok, YouTube or Instagram. You get a page like this one.

© 2026 TranslateMom Transcripts Sources Pricing Legal