Àríwísí ẹbí Seun Kuti lórí Wizkid àti àwọn ègún

Eyin family Seun Kuti.

Se te e ma ma wo egbon yin ran lele,

tan ma wo ja lo?

To ran fi 7 days 7 night,

won fi n pile were.

Won sa t'aridi lo bi atari oloru,

won wa ranju bi kankan at'emo re.

Alaye run bi asonu agbo,

e n fun awon omo olomo ni adura epe yen.

Ko ni ye yin, ko ni ye baba yin, patapata gigan yen, mo pe ori yin buru.

Ti o ba se ti Wizkid, ta lo ran fe l'anse?

Se e ro pe boya 1990 la wa ni?

Ti yin fe ta sha.

Le n se adura epe yen.

Ki lo de? Ki lo ra n gba

yin t'e o sanwo?

Ki lo le to yen?

Te e le ti e moju kuro.

Baba yin s'ori ire to be ni,

aye ni yin lara to yen.

Be l'ori ire

baba yin po to.

Mo ro pe boya e ri nkankan jogun ju patapata gigan osi yen lo,

ati igbo o were.

Mo pe ori yin buru.

Le n se adura epe yen.

Ojo te ba tun se epe mi,

ati eyin o, ati awon omo yin o,

ati baba yin Fela Anikulapo.

Epe mo fi ma pa yin.

E ni se ori ire.

E wa n s'ori buruku,

awon family yin kankan mo ri won comment section, e jo n sofo.

Eyan... He's just protecting his father's name.

E jo, e so fun mi, eni to ever...

To gbe camera ri,

to b'oruko baba e je.

E wa so fun mi,

e jade ke wa so.

Wizkid literally

has this man tattoo

on his body.

Like, you know... Get the fuck out of here.

Like egbon yen, mo ti e ma n ro pe boya opolo kan wa lori won ni.

E se daadaa rara.

E je fura s'egbon yen, won le ti lo won.

E n se bi eni

t'oruko e wa n'itele agbo nibikan.

Ori yin buru.

E n se adura epe,

bawo ni? Ko ni da fun eyin . E... owo po fun eyin le joko ori buruku sinu ile le n

se. E n se adura epe fun omo olomo. Omo to n hustle.

Omo to ti... to ti kuro l'odo yin tipe.

Eyin te ye ke reku, ke ma sunkun kiri,

ke ni ki lo se yin?

Ke ni tiyin ti ta ni.

Ko ni ye yin, ko ni...

Te ba fun awon omo olomo l'epe,

awon omo tiyin gan ma gbe epe.

E ni je eyan.

Mo bo l'ori buruku ni yin.

Se PR yin niyen?

98% PR yin niyen?

Ti yin ti ta danu.

End of transcript · 439 words

Transcribed with TranslateMom. Paste any video link to get subtitles and a transcript in your language.

iPhone app Translate videos on your iPhone Paste a TikTok, Instagram or X link, add subtitles in your language and save the video to Photos.

Made with TranslateMom

TranslateMom transcribes and translates videos from X, TikTok, YouTube and Instagram. Paste a link and you get a page like this one, in your language.

© 2026 TranslateMom · AI video translation and subtitles Transcripts Sources Pricing Legal