0:00

Orílè-èdè Nàìjíríà àì kí ń ṣe ọlọ́rọ̀ epo.

0:03

Nàìjíríà o kín ń ṣe oil rich nation. Mo fẹ jẹ́ kí gbogbo wa mọ bẹ́ẹ̀ pé ilẹ̀ Nàìjíríà àì kí ń ṣe oil rich nation. Í pé ká wá sọ í pé, eh, ìlú wa ọlọ́rọ̀ epo ni wa. A ní, eh, ọrọ epo gan, a ni.

0:19

Àná kan manage ni. Ọrọ epo ni ohun tó ń pè ní ọrọ epo.

0:24

Oil rich nation, Nàìjíríà ò sínbẹ̀. Ìjiyàn tí mo fẹ́ mú wá nìyẹn, àmọ́ ẹ máa bá mi bọ̀ kí ó lè jọ yé gbogbo wa.

0:33

Sẹ́rí nínú ìjiyàn yìí, lóòótọ́ Nàìjíríà ní epo tí a ń gbọ́n. Èyí tí a ń gbọ́n lójoojúmọ́.

0:41

Ó wà ní South South, àwọn South South, Niger Delta sé yẹn.

0:45

Sé wá rí epo yìí, tá bá ní ká ṣe, ẹ mọ pé Nàìjíríà ò ṣe ọlọ́rọ̀ epo. Í pé a ní ọrọ̀ epo, ìyá n t'óru, à ń ṣe ọlọ́rọ̀ epo.

0:52

Gẹ́gẹ́ bí àwọn èèyàn ṣe máa ń sọ pé, "a dẹ̀ lé epo, owó epo wá, owó epo wá", ẹjẹ́ má máa pa irọ́ fúnra wa. A ò ṣe ọlọ́rọ̀ epo. Àwa náà kan wà nínú àwọn ìlú tó lé epo ni.

1:04

Àti ká wá nǹkan mí bí owó orí, bí àwọn nǹkan mí.

1:08

Ìdí ni pé lọ́rílèèdè Nàìjíríà, ẹ jẹ́ kí n ṣe báyìí pé epo tí à ń rí ní ojúmọ́, average, wọn ṣe, ó máa ń wálẹ̀ ó máa ń lọ sókè. Nígbà tí a yẹ̀ wò ó jẹ́, eh, one point five million barrel per day up to one point seven million barrel per day. Barrel ni wọ́n fi ń ṣe kó ṣe gallon. Wọ́n wá ní one point five million àbí one point-- láàrin

1:33

one point five sí one point seven million barrel per day.

1:37

Ẹ wá jẹ́ ká di one point seven. Ó máa ń wálẹ̀ jù bẹ́ẹ̀ lọ́gbà mí òpápa ju lọ láyé àwọn Buhari ìgbà náà, ìgbà tí wọ́n sì ń jí epo wà tó ń ta fáwọn ìlú òkè òkun.

1:48

Nàììjíríà ń rí epo one point fi-- one point seven million barrel per day. Iyẹn ni ojúmọ́ kan.

1:56

Saudi Arabia, àwọn ń gbọ́ epo nílùú wọn, epo tó jẹ́ six million two hundred and-- six point two hundred and thirty eight million per day.

2:06

Ni Saudi Arabia six point two hundred and thirty eight million barrel per day ní ọjọ́ kan. Óun ni wọ́n ń gbọ́n.

2:14

Sé ẹ ń gbọ́ mi? Àwọn Qatar, ìlú Qatar, àwọn máa ń gbọ́n, wọ́n ń gbọ́n epo five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan. Qatar wọ́n ń gbọ́n epo five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan.

2:29

Mo mọ̀ mọ̀ mú ìlú tó ní epo púpọ̀. Mo tún mú ìlú tí ò gbọ́n púpọ̀ tó wá wá. Kí àgbọ́yé yẹn kó lè dá, kó lè gbo-- kó lè yé gbogbo wa. ẹ rí UAE àwọn produce three point eight million barrel per day.

2:45

Epo tí wọ́n ń rí lójúmọ́ barrel three point eight million barrel per day. Sé o ti yé yin? ẹ wá jẹ́ ká ṣe ìṣirò ẹ̀. Sé ẹ rí ilẹ̀, orílè-èdè Nàìjíríà, a ní èèyàn two hundred and forty four million.

3:00

Two hundred and forty four million the-- ó wà documented ìbáyìí.

3:04

Tẹ bá wò wípé a jẹ́ iye èèyàn tó ń gbé nílùú wa, t'a jọ mọ ìlú two hundred and forty four million people.

3:10

A dẹ̀ ń rí epo one point seven million per day ní ọjọ́ kan. Saudi Arabia tó ń rí, tó ní epo six point two hundred and thirty eight million barrel lójúmọ́ kan. Àwọn ní population, èròlú wọn ó jẹ́ thirty five point two million.

3:31

Sé ẹ ń gbọ́ o? Thirty five point two million.

3:34

Díẹ̀ lọ bí i Jekọ lọ. Qatar tó ń rí epo five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan.

3:41

Five hundred and eighty thousand barrel ní ọjọ́ kan. Ẹ mọ̀ pé ko tó one million.

3:46

Ní ìlú wọn, wọ́n jẹ́ three point two million.

3:49

Àwọn aráàlú wọn, wọ́n jẹ́ three point two million.

3:52

Sé wá rí UAE, United Arab Emirate, mo mọ̀ mọ̀ mú àwọn tí ẹ máa ń fi wa wé yẹn, mo mọ̀ mọ̀ mú wọn wá ni. Í pé bí àwọn yẹn owó epo lọ́ n fi ṣe bá kẹlé gba wa ayé. Ìdí-- àwọn UAE ní epo three point eight million lọ ń produce barrel lọ.

4:10

Iye èèyàn tó wà nílùú wọn jẹ́ eleven point six million.

4:14

Iye èèyàn tó wà nílùú wọn ó jẹ́ eleven point six million. Sé wá ń gbọ́? ẹ wá jẹ́ ká wá sí Nàìjíríà.

4:23

A ń rí epo one point seven million. Ẹ jẹ́ ká wá pín one point seven million yẹn ká fi divide the two hundred and forty four million.

4:31

Barrel, iye barrel mélòó ló kan èèyàn kankan.

4:34

Ẹ jẹ́, òun ni mo kọ. Zero point zero zero six nine barrel. Zero point zero zero six nine barrel fún èèyàn kan.

4:46

Ṣọ̀rọ̀ yẹn ye. Òun ni fún èèyàn kan. Saudi, ilẹ̀ Saudi Arabia tí a bá ṣí epo tó ń rí six point two hundred and thirty eight million barrel ní ọjọ́ kan, òun dè ní èrò tó ń gbé lù àwọn ará ìlú ẹ jẹ́ thirty two-- thirty five point two million.

5:05

Iye tí Saudi, iye tí ara ìlú kọ̀ọ̀kan máa ń rí ó jẹ́ zero point one hundred and seventy eight.

5:11

Zero point one hundred and seventy eight fún èèyàn kan.

5:15

Qatar, iye tó ó máa ń rí fún èèyàn kan ó jẹ́ zero point one eighty one fún èèyàn kan. Zero point one eighty one.

5:23

Sé ẹ rí Qatar yẹn tí ẹ bá gbàgbé ọmọ ló ń produce, ó ń rí epo five hundred and eighty thousand barrel.

5:30

Population wá jẹ́ three point two million.

5:32

Tá bá wá ṣí five hundred and eighty tá a fi pín, divide rẹ̀ sí three point two million àwọn aráàlú ẹ.

5:39

Epo tí ó ń rí ní Qatar èèyàn kan, ohun tó máa ń kọ èèyàn kan ni zero point one eighty one barrel fún èèyàn kan. UAE ló ń rówó jù. Torí UAE yẹn, òun, epo tí UAE ń rí three point eight million barrel ló ń rí lójúmọ́. Aráàlú ẹ lẹ́ẹ̀ jẹ́ eleven point six million.

5:58

Ohun tí UAE wà ń rí ò jẹ́ zero point three two seven ní èèyàn kan máa ń rí.

6:02

Iyẹn barrel èèyàn kan. Ẹ jẹ́ wá mú báyìí.

6:05

Iye tí èèyàn kan ní Nàìjíríà tí ó máa ń rí, tá bá pín eyi, owó, eh, epo tá ń rí sórí gbogbo àwọn tó bá ta, tá bá pín Èèyàn kan máa rí naira and forty five naira.

6:19

Iyẹn fún epo zero point zero zero six nine yẹn.

6:23

Baba wa ojúmọ̀ bá ṣe ń ta yẹn ká máa wá pín fún aráàlú kan.

6:27

Iye tó kun èèyàn kan. Nine point-- eh, nine hundred and forty five naira ló kun èèyàn kan. Nine hundred and forty five naira.

6:36

Nínú ìrìn tó orí ọlọ́pa wà níbẹ̀, wọ́n máa san owó oṣù.

6:40

Àwọn tó ń dáàbò bọ̀ ẹ, nine hundred and forty five naira.

6:44

Gbogbo ìlú bọ́ ṣe ń to, rédíò, gbogbogbà, gbogbo awo, àwọn nǹkan yìí tí ìjọba ń ṣe àbí wọ́n ṣe, iṣẹ́ ìjọba kankan ò dọdú etí tí tó ń rìn.

6:53

Se nine hundred and forty five òní. Se wá rí ní United Arab Emirate, owó tí èèyàn kan máa rí, owó tí èèyàn kan máa rí ó jẹ thirty one point eighty two dollar. Ka ní thirty two dollar. Èèyàn kan máa rí.

7:08

Tọ bá pín epo tó ń rí lójúmọ́, tó bá gbọ́ sórí èèyàn kankan, ẹni kankan á gba thirty two dollar.

7:14

Taa bá ṣe thirty two dollar yẹn sí náírà, ó máa jẹ forty two thousand three hundred and thirty fún èèyàn kan.

7:22

Forty two thousand three hundred and thirty fún èèyàn kan.Ẹ jọ, tọ́ mọ̀lú wọn ò bá ṣiṣẹ́, tó bá fún lówó, ṣe ó tó bẹ́ àbí ò tó bẹ́?

7:29

Wọ́n dẹ̀ tún ní gold, wọ́n tún láwọn ọrọ̀ ajé ni.

7:31

Kẹ́ ẹ lè mọ̀ wípé àwọn ìlú tó ní ọrọ̀ epo nìyẹn.

7:35

Epo tá ń gbọ́ lẹ̀ ń wò pé ó pọ̀. Ẹ̀wọ̀ yẹ èèyàn tí ìjọba fẹ́ katà fún, tó fẹ́ bù katà fún.

7:42

Ẹ̀wọ̀ yẹ bù katà tó wà nínú ìjọba wa. Ẹ̀wọ̀ yẹ bù katà ìhun tí ìjọba wa ń gbọ́ iye èrò tó fẹ́ gbọ́tí ẹ̀. ìdí nìyẹn tó wọ̀nyí ò ṣe ná.

7:52

Ẹ wá ní òkè, ìgbà tí wọ́n ń wá, tí wọ́n wá jẹ́ owó tó kàn èèyàn kan, epo kan pàá bàárẹ́. Ó wá jẹ́ nine, ní Nigeria ni bíí nine hundred and forty five naira. ẹ wá ní kí wọ́n máa subsidize rẹ̀, kí wọ́n máa fowó òkun pa síi.Ẹ jọ, ọ̀fẹ́ ló máa jẹ yẹn.

8:07

Iṣẹ́ tó ní ẹ fẹ́ ṣe fún gbogbo wa nínú ìlú u wa ó pọ̀.

8:12

Taa bá ṣe owó epo yẹn lórí èèyàn kankan, ó yá.

8:16

Tọ bá fún ògbe èèyàn lówó yẹn, iṣẹ́ tó fẹ́ ṣe nínú ìlú ń kọ ìdí tó ṣe le láti san owó ìkúnpa owó epo fún wa lórílẹ̀èdè Nigeria ni mo ṣàlàyé yìí. Ẹ̀yin èèyàn, mí à jẹ́ kí ẹnìkan wá, kó má ní òun á dá owó epo padà. Irọ̀lẹ́ ni ìyẹn ń pa.

8:31

Ó kàn máa kó wa sí gbèsè. Ó máa kó wa sí gbèsè ni.

8:35

Gbèsè tá tú máa máa san òní Tinubu san lọ́wọ́, ó ń yá ó fi ń ṣe ọ̀nà.

8:39

Ọ̀nà tó ń rí táwọn ń dá tí ògbe ń dá làwọn òṣìṣẹ́ àwọn ilé iṣẹ́ ṣe wá láti ìta ná wá ń dá ilé iṣẹ́ lẹ̀.

8:46

Wọn ò ní pàrí iṣẹ́ yẹn tó bá bẹ̀rẹ̀ tọ́ sí ibi padà. Gbogboṣé wọn ò ní rówó ṣe.

8:51

Wọn ò ní rówó ṣe mọ́. Àlàyé tí mo ní mú wá ni pé ilẹ̀ Nàìjíríà o, a ò ṣe ọlọ́rọ̀ epo. Àwa náà ní epo. Epo kan ń dá sí owó tí a ń rí ni. So kò ṣe pé ká má san owó orí.

9:03

Kò yẹ bẹ́. Fún ètò ààbò àti ìlú tó péye kò yẹ pé ká má san owó orí. Àlàyé tí mo ní mú wá. Ẹ má bíi mo wà very very emotional torí mo má ń ka comment, mo mọ̀ pé à, ohun tó pọ̀ tí ò yẹ àwọn èèyàn mi, ó pọ̀ gan. Jẹ́ kí ń clear, kí i ní kí ń la.

9:18

Ẹ jẹ́ àwọn èèyàn ṣe, ẹ bá mi like ẹ. Àbí kílé ni náà tú rí fíìmù tí mo sọ.

9:21

Ṣé Nàìjíríà jẹ́ ọlọ́rọ̀ epo pẹ̀lú ìṣirò tí mo gbé wá léyìí, tí mo gbé wá yìí? Tẹ́ ì bá, tẹ́ ì bá ṣe èrò, ẹ jọ, ẹ jẹ́ ká mọ̀ ní comment section.

9:30

Ẹ bá like, ẹ share, ẹ follow. Ẹ má gbàgbé láti subscribe ní YouTube àti Facebook. Ẹ ṣe

End of transcript · 1,805 words

iPhone app Translate videos on your iPhone Paste a TikTok, Instagram or X link, add subtitles in your language and save the video to Photos.

Made with TranslateMom

TranslateMom transcribes and translates videos from X, TikTok, YouTube and Instagram. Paste a link and you get a page like this one, in your language.

Transcribed with TranslateMom. Paste any video link to get subtitles and a transcript in your language.

© 2026 TranslateMom · AI video translation and subtitles Transcripts Sources Pricing Legal